ГлавнаяИсполнителиJW Broadcasting - YR-ЙорубаÌyanu Ni Iṣẹ́ Rẹ
название:

Ìyanu Ni Iṣẹ́ Rẹ


автор:

JW Broadcasting - YR-Йоруба


рейтинг: ★★★★★ / 5.4 / 1387 просмотров
1. Ọ̀pọ̀ ìbùkún ni Ìjọba rẹ ti mú wá.
Ó ti jẹ́ kí n ní Bíbélì, kí n sì mọ òtítọ́.

O tún yan ẹrú olóòótọ́, ó ń fọ̀rọ̀ rẹ yé wa.

O fàwọn alàgbà kẹ́ mi, wọ́n ń fìfẹ́ tọ́jú mi.

Àwọn àpéjọ wa máa ń ládùn, ó máa ń lóyin.

Ọdọọdún ni mo máa ń sọ pé, “Tọdún yìí ló dùn jù!”

Ohun tí à ń kọ́ nípàdé fi hàn pó o nífẹ̀ẹ́ wa,

Ó ń kọ́ mi bí màá ṣe wàásù, kí n sì máa ṣèfẹ́ rẹ.

(ÈGBÈ)

Ìyanu niṣẹ́ rẹ,

sì mọyì Ìjọba rẹ.

Ọ̀pọ̀ nǹkan ló ti ṣe.

 [bad word] tó dára ni ọ, ọkàn wa balẹ̀ gan-an.

À ń retí ìbùkún tí Ìjọba rẹ yóò mú wá.

2. Ọlá ńlá lo dá wa pé ká máa bá ọ ṣiṣẹ́,
À ń fìtara wàásù ká lè fi hàn pá a nífẹ̀ẹ́ rẹ.

Ò ń fi Ọ̀rọ̀ rẹ yé wa, ò ń fi wá lọ́kàn balẹ̀,

Ọ̀rọ̀ rẹ ń jẹ́ káyé wa dáa; ó ń fòtítọ́ hàn wá.

Tí mo bá ń gbọ́ orin wa, ó máa ń wọ̀ mí lọ́kàn.

Ìjọsìn Ìdílé wa ń ran ìdílé wa lọ́wọ́.

Ibi yòówù ká wà, èdè yòówù kí a máa sọ,

Ọmọ ìyá ni gbogbo wa, irú èyí ṣọ̀wọ́n!

(ÈGBÈ)

Ìyanu niṣẹ́ rẹ,

sì mọyì Ìjọba rẹ.

Ọ̀pọ̀ nǹkan ló ti ṣe.

 [bad word] tó dára ni ọ, ọkàn wa balẹ̀ gan-an.

À ń retí ìbùkún tí Ìjọba rẹ yóò mú wá.

Послушать/Cкачать эту песню
Mp3 320kbps на стороннем сайте
А как ты думаешь, о чем песня "Ìyanu Ni Iṣẹ́ Rẹ" ?
2010-2020 © WebKind.Ru Тексты песен